Numbers 3:17-20

17 aWọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi:
Gerṣoni, Kohati àti Merari.
18Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni:
Libni àti Ṣimei.
19Àwọn ìdílé Kohati ni:
Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.
20Àwọn ìdílé Merari ni:
Mahili àti Muṣi.

Wọ̀nyí ni ìdílé Lefi gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn.
Copyright information for YorBMYO